November Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé November-December 2021 November 1-7 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Fọgbọ́n Pín Ilẹ̀ Fáwọn Èèyàn Rẹ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI A Dúpẹ́ Lọ́wọ́ Jèhófà Torí Ìfẹ́ Tẹ́ Ẹ̀ Ń Fi Hàn November 8-14 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Èdèkòyédè Kan Tó Wáyé November 15-21 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ìmọ̀ràn Tí Jóṣúà Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kẹ́yìn November 22-28 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ìtàn Tó Ń Mórí Ẹni Wú Nípa Ọkùnrin Onígboyà Kan MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Jẹ́ Kí Jèhófà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nípasẹ̀ Àdúrà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bá A Ṣe Lè Darí Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Pápá Lọ́nà Tá Ṣe Àwọn Ará Láǹfààní November 29–December 5, 2021 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Gba Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Là Nípasẹ̀ Àwọn Obìnrin Méjì MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Báwo Làwọn Arábìnrin Ṣe Lè Ṣe Púpọ̀ Sí I Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà? December 6-12 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Lọ Lo Agbára Tí O Ní” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀mí Mímọ́ Mú Kí Wọ́n Ṣe Iṣẹ́ Tí Kò Rọrùn Láṣeyọrí December 13-19 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ó Sàn Kéèyàn Lẹ́mìí Ìrẹ̀lẹ̀ Ju Kó Jẹ́ Agbéraga December 20-26 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ẹni Tẹ̀mí ni Jẹ́fútà December 27, 2021–January 2, 2022 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ohun Táwọn Òbí Lè Rí Kọ́ Látinú Ohun Tí Mánóà àti Ìyàwó Rẹ̀ Ṣe MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Dá Kẹ́kọ̀ọ́ MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ