ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 10
  • December 6-12

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • December 6-12
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 10

December 6-12

ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 6-7

  • Orin 38 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Lọ Lo Agbára Tí O Ní”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Ond 6:27​—Báwo ni ohun tí Gídíónì ṣe ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù? (w05 1/15 26 ¶6)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 6:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Bíbélì​—Ro 15:4. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì, kó o sì ṣàlàyé bó ṣe lè wà á jáde lórí ìkànnì wa. (th ẹ̀kọ́ 15)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 104

  • “Ẹ̀mí Mímọ́ Mú Kí Wọ́n Ṣe Iṣẹ́ Tí Kò Rọrùn Láṣeyọrí”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Bá A Ṣe Ṣe Fídíò “The New World Society in Action.”

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 17 ¶1-8 àti fídíò ohun tó wà ní orí 17

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 8 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́