ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 8
  • November 29–December 5, 2021

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 29–December 5, 2021
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 8

November 29–December 5

ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 4-5

  • Orin 137 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Gba Àwọn Èèyàn Rẹ̀ Là Nípasẹ̀ Àwọn Obìnrin Méjì”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Ond 5:20​—Báwo làwọn ìràwọ̀ ṣe jà látọ̀run nítorí Bárákì? (w05 1/15 25 ¶5)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 4:1-16 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní Ilé Ìṣọ́ No. 2 2021. (th ẹ̀kọ́ 1)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún onílé ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 4)

  • Àsọyé: (5 min.) w06 3/1 28-29​—Àkòrí: Kí Nìtumọ̀ Ohun Tí Bíbélì Sọ Pé Káwọn “Obìnrin Máa Dákẹ́ Nínú Ìjọ”?—1Kọ 14:34. (th ẹ̀kọ́ 14)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 84

  • “Báwo Làwọn Arábìnrin Ṣe Lè Ṣe Púpọ̀ Sí I Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Jèhófà?”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò “Àwọn Obìnrin Tó Ń Ṣiṣẹ́ Kára Nínú Olúwa.”

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 16 ¶14-20 àti àpótí 16B

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 27 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́