ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 6
  • November 22-28

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 22-28
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 6

November 22-28

ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 1-3

  • Orin 126 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ìtàn Tó Ń Mórí Ẹni Wú Nípa Ọkùnrin Onígboyà Kan”: (10 min.)

    Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Ond 2:10-12​—Ìkìlọ̀ wo ló wà nínú ìtàn yìí? (w05 1/15 24 ¶7)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 3:12-31 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • “Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Jẹ́ Kí Jèhófà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nípasẹ̀ Àdúrà”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Lo Àwọn Nǹkan Tí Jèhófà Pèsè—Àdúrà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ ní ẹ̀kọ́ 02 àti kókó 1-3 (th ẹ̀kọ́ 11)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 53

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Máa Ṣe Dáadáa Lóde Ẹ̀rí: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, tó bá ṣeé ṣe pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n ní ìbéèrè yìí: Báwo la ṣe lè múra sílẹ̀ fún iṣẹ́ ìwàásù? Báwo la ṣe lè múra lọ́nà tó bójú mu àti níwọ̀ntúnwọ̀nsì tá a bá ń lọ sóde ẹ̀rí? Báwo la ṣe lè máa hùwà lọ́nà tó bójú mu lóde ẹ̀rí?

  • “Bá A Ṣe Lè Darí Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Pápá Lọ́nà Tá Ṣe Àwọn Ará Láǹfààní”: (10 min.) Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Jẹ́ káwọn ará sọ ìdí tó fi yẹ ká máa tètè dé sípàdé iṣẹ́ ìsìn pápá.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 16 ¶9-13 àti àpótí 16A

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 29 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́