ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 January ojú ìwé 3
  • January 10-16

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 10-16
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 January ojú ìwé 3

January 10-16

ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 17-19

  • Orin 88 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Téèyàn Bá Rú Òfin Ọlọ́run, Àbájáde Ẹ̀ Kì Í Dáa”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Ond 19:18​—Kí nìdí tá a ṣe fi orúkọ Jèhófà sínú ẹsẹ Bíbélì yìí nínú Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun tá a tún ṣe lọ́dún 2013 (w15 12/15 10 ¶6)

    • Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 17:1-13 (th ẹ̀kọ́ 2)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Ọlọ́run Ń Bójú Tó Wa​—Jer 29:11. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 6)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà fún ẹni náà ní ìwé pẹlẹbẹ Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! kó o sì bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní ẹ̀kọ́ 01. (th ẹ̀kọ́ 13)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 89

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Máa Ṣègbọràn sí Àwọn Òbí Rẹ: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, tó bá ṣeé ṣe, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan, kó o sì béèrè àwọn ìbéèrè yìí lọ́wọ́ wọn: Kí ni mọ́mì Kọ́lá ní kó ṣe àmọ́ tí kò ṣe? Kí ni Kọ́lá ṣe tó fi hàn pé ó ṣàtúnṣe? Kí nìdí tó fi yẹ kó o máa gbọ́ràn sáwọn òbí ẹ lẹ́nu?

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 18 ¶16-25

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 150 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́