January Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé January-February 2022 January 3-9 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Kórìíra Àwọn Ọ̀dàlẹ̀ January 10-16 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Téèyàn Bá Rú Òfin Ọlọ́run, Àbájáde Ẹ̀ Kì Í Dáa January 17-23 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Wádìí Lọ́dọ̀ Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Jẹ́ Kó Túbọ̀ Dá Wa Lójú Pé Ọlọ́gbọ́n Ni January 24-30 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn Sáwọn Míì MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Kó Dá Ẹ Lójú Pé Ìfẹ́ Tí Jèhófà Ní sí Ẹ Kò Ní Yẹ̀ Láé January 31–February 6 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Bó O Ṣe Lè Ṣe Orúkọ Rere fún Ara Ẹ TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Wá Sípàdé February 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Sọ Gbogbo Ohun Tó Wà Lọ́kàn Ẹ fún Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Máa Sọ Ohun Tó Wà Lọ́kàn Yín Fáwọn Òbí Yín February 14-20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Máa Ń Gba Tiwa Rò MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ohun Tá A Lè Kọ́ Lára Sámúẹ́lì February 21-27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ta Ni Ọba Rẹ? February 28–March 6 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Sọ́ọ̀lù Nírẹ̀lẹ̀, Ó Sì Mọ̀wọ̀n Ara Ẹ̀ Níbẹ̀rẹ̀ TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Yẹra fún Ẹgbẹ́ Búburú MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ