ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 January ojú ìwé 8
  • January 31–February 6

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • January 31–February 6
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 January ojú ìwé 8

January 31–February 6

RÚÙTÙ 3-4

  • Orin 39 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Bó O Ṣe Lè Ṣe Orúkọ Rere fún Ara Ẹ”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Ìyebíye Míì: (10 min.)

    • Rut 4:6​—Ọ̀nà wo ni olùtúnrà fi lè “run” ogún rẹ̀ tó bá ṣe ìtúnrà? (w05 3/1 29 ¶4)

    • Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Rut 4:7-22 (th ẹ̀kọ́ 5)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • “Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀​—Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Wá Sípàdé”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Máa Wá Sípàdé.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 03 kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 8)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 24

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 19 ¶16-21 àti àpótí 19B

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 144 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́