February 7-13
1 SÁMÚẸ́LÌ 1-2
Orin 44 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Máa Sọ Gbogbo Ohun Tó Wà Lọ́kàn Ẹ fún Jèhófà”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Sa 2:10—Kí nìdí tí Hánà fi gbàdúrà sí Jèhófà pé kó “fún ọba rẹ̀ ní agbára” nígbà tó jẹ́ pé kò sí èèyàn kankan tó jẹ́ ọba ní Ísírẹ́lì? (w05 3/15 21 ¶5)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 1:1-18 (th ẹ̀kọ́ 12)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3)
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà fún onílé ní ìwé pẹlẹbẹ Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! Ní ṣókí, ẹ jíròrò “Bó O Ṣe Lè Jàǹfààní Púpọ̀ Látinú Ẹ̀kọ́ Bíbélì Yìí.” (th ẹ̀kọ́ 20)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ẹ̀kọ́ 03 kókó 5 (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Máa Sọ Ohun Tó Wà Lọ́kàn Yín Fáwọn Òbí Yín”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Ìgbà Ọ̀dọ́ Mi—Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀?
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 20 ¶1-8 àti fídíò ohun tó wà ní orí 20
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 113 àti Àdúrà