ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 May ojú ìwé 15
  • “Ìfẹ́ . . . Kì Í Gbéra Ga”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ìfẹ́ . . . Kì Í Gbéra Ga”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ‘Ẹ Máa Rìn Nínú Ìfẹ́’
    Sún Mọ́ Jèhófà
  • Ìfẹ́ (Agape)—Ohun Tí Kò jẹ́ Àti Ohun Tí Ó Jẹ́
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1993
  • Kí Ìfẹ́ Máa Gbé Yín Ró
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2001
  • “Ìfẹ́ Kì Í Kùnà Láé”—Ìwọ Ńkọ́?
    Jí!—1998
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 May ojú ìwé 15
Àwòrán: 1. Arákùnrin kan ń gbàdúrà kó tó bẹ̀rẹ̀ sí í ka Bíbélì. 2. Ó ń tún Gbọ̀ngàn Ìjọba ṣe. 3. Òun àtìyàwó ẹ̀ lọ kí arábìnrin àgbàlagbà kan nílé ìwòsàn.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

“Ìfẹ́ . . . Kì Í Gbéra Ga”

Ìfẹ́ kì í jẹ́ ká máa ro ara wa ju bó ṣe yẹ lọ. (1Kọ 13:4) Tá a bá nífẹ̀ẹ́ àwọn ará wa, a ò ní máa ronú pé a sàn jù wọ́n lọ. Bákan náà, ibi tí wọ́n dáa sí làá máa wò, àá sì máa lo ẹ̀bùn àbínibí èyíkéyìí tá a bá ní láti ràn wọ́n lọ́wọ́. (Flp 2:3, 4) Bá a bá ṣe túbọ̀ ń fìfẹ́ yìí hàn, bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà á ṣe túbọ̀ máa lò wá lẹ́nu iṣẹ́ rẹ̀.

Ẹ WO FÍDÍÒ NÁÀ MÁ GBÀGBÉ OHUN TÍ ÌFẸ́ MÁA Ń ṢE​—KÌ Í GBÉRA GA, KẸ́ Ẹ SÌ DÁHÙN ÀWỌN ÌBÉÈRÈ YÌÍ:

  • Àwọn ẹ̀bùn wo ni Ábúsálómù ní?

  • Báwo ni Ábúsálómù ṣe ṣi ẹ̀bùn rẹ̀ lò?

  • Báwo la ṣe lè yẹra fún ìgbéraga?​—Ga 5:26

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́