May Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, May-June 2022 May 2-8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ọgbọ́n Tí Dáfídì Dá Kó lè Dáàbò Bo Àwọn Èèyàn Ọlọ́run May 9-15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Gbára Lé Jèhófà Tó O Bá Ní Ẹ̀dùn Ọkàn May 16-22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Kí La Rí Kọ́ Látinú Orin Tí Dáfídì Pè Ní “Ọrun”? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Ìfẹ́ . . . Kì Í Yọ̀ Lórí Àìṣòdodo” ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Ìfẹ́ . . . Máa Ń Retí Ohun Gbogbo” May 23-29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Nígbà Gbogbo MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀ fún Rògbòdìyàn Tó Lè Ṣẹlẹ̀? May 30–June 5 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Bá Dáfídì Dá Májẹ̀mú MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Lo Àwọn Ohun Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Lágbègbè Rẹ Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù June 6-12 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Dáfídì Fi Ìfẹ́ Tí Kì Í Yẹ̀ Hàn June 13-19 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Má Ṣe Gba Èròkerò Láyè MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Kó Ara Ẹ Níjàánu Tí Èròkerò Bá Ń Wá Sí Ẹ Lọ́kàn June 20-26 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ámínónì Mọ Tara Ẹ̀ Nìkan, Ìyẹn sì Yọrí sí Àdánù Ńlá MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Fi Ìwé “Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!” Ran Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Nígbàgbọ́ Nínú Jèhófà àti Jésù June 27–July 3 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ìgbéraga Mú Kí Ábúsálómù Ṣọ̀tẹ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Ìfẹ́ . . . Kì Í Gbéra Ga” MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ