ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 May ojú ìwé 6
  • May 23-29

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • May 23-29
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 May ojú ìwé 6

May 23-29

2 SÁMÚẸ́LÌ 4-6

  • Orin 135 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Máa Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Nígbà Gbogbo”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • 2Sa 6:8, 9​—Kí la rí kọ́ látinú bí Dáfídì ṣe hùwà pa dà nígbà tí inú bí Jèhófà? (w96 4/1 29 ¶1)

    • Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Sa 4:1-12 (th ẹ̀kọ́ 10)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 12)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 9)

  • Àsọyé: (5 min.) w05 10/1 23-24 ¶14-15 ​—Àkòrí: “Ẹ Bẹ̀rù Ọlọ́run, Kí Ẹ sì Fi Ògo Fún Un.”​—Ifi 14:7. (th ẹ̀kọ́ 19)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 143

  • “Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀ fún Rògbòdìyàn Tó Lè Ṣẹlẹ̀?”: (15 min.) Ìjíròrò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ṣé O Ti Múra Sílẹ̀ De Àjálù? Mẹ́nu kan àwọn ìtọ́ni tí ẹ̀ka ọ́fíìsì ti fún un yín àtèyí tí ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà fohùn ṣọ̀kan lé lórí, ìyẹn tó bá wà.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 05

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 96 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́