ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 September ojú ìwé 8
  • October 2-8

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • October 2-8
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 September ojú ìwé 8

October 2-8

JÓÒBÙ 1-3

  • Orin 141 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Máa Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Job 1:10—Báwo ni ohun tó wà nínú ẹsẹ yìí ṣe jẹ́ ká lóye ọ̀rọ̀ Jésù tó wà ní Mátíù 27:46? (w21.04 11 ¶9)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 3:​1-26 (th ẹ̀kọ́ 12)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Sọ fún ẹni náà nípa ìkànnì wa, kó o sì fún un ní káàdì ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 9)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣe bíi pé ẹ wo fídíò Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì? (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó) (th ẹ̀kọ́ 20)

  • Àsọyé: (5 min.) w22.01 11-12 ¶11-14—Àkòrí: Jẹ́ Olùkọ́ Tó Mọ̀ọ̀yàn Kọ́ Bíi Ti Jémíìsì—Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Kó O Sì Máa Sọ Òótọ́ Ọ̀rọ̀. (th ẹ̀kọ́ 18)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 21

  • Mo Rò Pé Mo ti Ní Gbogbo Nǹkan: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi wọ́n pé: Kí ló mú kí Arákùnrin Birdwell gbà pé òun “ti ní gbogbo nǹkan”?

    Báwo lohun tó wà nínú Mátíù 6:33 ṣe ràn án lọ́wọ́?

    Àwọn nǹkan míì wo lo tún rí kọ́ nínú ohun tó ṣẹlẹ̀ sí ìdílé Birdwell?

  • “Máa Lo Abala Ìbẹ̀rẹ̀ Orí Ìkànnì JW.ORG Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù”: (5 min.) Ìjíròrò.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 59 kókó 6 àti kókó pàtàkì, kí lo rí kọ́? àti ohun tó yẹ kó o ṣe (30 min.)

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 129 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́