September Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, September-October 2023 September 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà September 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ran Àwọn Mí ì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà September 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Gbẹ́kẹ̀ Lé Jèhófà Tí Ẹnì Kan Bá Ń Halẹ̀ Mọ́ Ẹ September 25–October 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ó Lo Àṣẹ Tó Ní Láti Ran Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Lọ́wọ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn Tó Ń Ṣiṣẹ́ Kára fún Ire Àwọn Èèyàn Ọlọ́run October 2-8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Máa Fi Hàn Pé O Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Tọkàntọkàn MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Lo Abala Ìbẹ̀rẹ̀ Orí Ìkànnì JW.ORG Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìwàásù October 9-15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ṣọ́ra Fáwọn Ọ̀rọ̀ Tí Kì Í Ṣòótọ́ October 16-22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ohun Tó O Lè Ṣe Tí Gbogbo Nǹkan Bá Tojú Sú Ẹ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Ń Gba Àwọn Tí Àárẹ̀ Bá Ẹ̀mí Wọn Là October 23-29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ìfẹ́ Jèhófà Tí Kì í Yẹ̀ Ń Dáàbò Bò Wá Lọ́wọ́ Irọ́ Sátánì MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ran Àwọn Tí Kò Ṣe Ẹ̀sìn Kankan Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Gbà Pé Ọlọ́run Wà October 30–November 5 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ohun Mẹ́ta Táá Jẹ́ Ká Ní Ọgbọ́n, Kó sì Ṣe Wá Láǹfààní MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Ran Àwọn Ọmọ Yín Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Ní Ọgbọ́n Ọlọ́run TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ