ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 September ojú ìwé 3
  • September 11-17

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • September 11-17
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 September ojú ìwé 3

September 11-17

Ẹ́SÍTÀ 3-5

  • Orin 85 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Ẹst 4:​12-16—Bíi ti Ẹ́sítà àti Módékáì, kí làwa náà lè ṣe ká lè jà fún òmìnira láti máa jọ́sìn Ọlọ́run láìsí ìdíwọ́? (kr 161 ¶14)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ẹst 3:​1-12 (th ẹ̀kọ́ 2)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Ìpadàbẹ̀wò: Ìjọba Ọlọ́run—Mt 14:​19, 20. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ṣàlàyé bá a ṣe máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì, kó o sì fún un ní káàdì ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 16)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 12 ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ àti kókó 1-3 (th ẹ̀kọ́ 15)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 65

  • Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Ẹ́sítà Jẹ́ Onígboyà: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà tó bá ṣeé ṣe, pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan, kó o sì bi wọ́n ní ìbéèrè yìí: Báwo lo ṣe lè fi hàn pé ó nígboyà bíi ti Ẹ́sítà?

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 57

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 125 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́