ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 September ojú ìwé 3
  • Ran Àwọn Mí ì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ran Àwọn Mí ì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ó Lo Àṣẹ Tó Ní Láti Ran Àwọn Èèyàn Ọlọ́run Lọ́wọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 September ojú ìwé 3

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà

Módékáì nígboyà, ó sì jẹ́ adúróṣinṣin sí Jèhófà (Ẹst 3:​2-4; it-2 431 ¶7)

Ó jẹ́ kí Ẹ́sítà mọ ohun tó máa ṣe kó lè ran àwọn èèyàn Ọlọ́run lọ́wọ́ (Ẹst 4:​7, 8; it-2 431 ¶9)

Ó gba Ẹ́sítà níyànjú pé kó nígboyà, kó sì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà (Ẹst 4:​12-14; ia 133 ¶22-23)

Àwòrán: 1. Alàgbà kan ń fún ọ̀dọ́kùnrin kan níṣìírí bí wọ́n ṣe wà lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù. 2. Ọ̀dọ́kùnrin náà ń kọ̀rọ̀ sí fọ́ọ̀mù Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere Ìjọba Ọlọ́run lórí ìkànnì. 3. Nígbà tó yá, arákùnrin náà kẹ́kọ̀ọ́ yege ní Ilé Ẹ̀kọ́ Àwọn Ajíhìnrere Ìjọba Ọlọ́run.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé ìwà àti ọ̀rọ̀ ẹnu mi máa ń gbé àwọn tó wà nínú ìjọ ró, ṣé ó sì máa ń jẹ́ kó wù wọ́n láti túbọ̀ lo ara wọn lẹ́nu iṣẹ́ Jèhófà?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́