ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 September ojú ìwé 4
  • Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ran Àwọn Mí ì Lọ́wọ́ Kí Wọ́n Lè Túbọ̀ Máa Lo Ara Wọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Jẹ́ Kí Jèhófà Tù Ẹ́ Nínú
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ṣé O Máa Ń Hùwà Láìronú?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 September ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀

Ẹ́sítà ṣe sùúrù kó tó sọ̀rọ̀ (Ẹst 7:2; ia 140 ¶15-16)

Ó fọgbọ́n sọ̀rọ̀, ó sì bọ̀wọ̀ fún ọba (Ẹst 7:3; ia 140 ¶17)

Ó sọ gbogbo bọ́rọ̀ ṣe rí láì fọ̀rọ̀ sábẹ́ ahọ́n sọ (Ẹst 7:4; ia 141 ¶18-19)

Inú ìyá kan àti ọmọbìnrin rẹ̀ ń dùn bí wọ́n ṣe ń sọ̀rọ̀, tí wọ́n sì ń dáná.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fara wé Ẹ́sítà tí mo bá ń bá àwọn mọ̀lẹ́bí mi sọ̀rọ̀?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́