ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 March ojú ìwé 14
  • Ṣé O Máa Ń Hùwà Láìronú?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé O Máa Ń Hùwà Láìronú?
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Máa Sọ Gbogbo Ohun Tó Wà Lọ́kàn Ẹ fún Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ábígẹ́lì Àti Dáfídì
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Ó Hùwà Ọlọgbọ́n
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 March ojú ìwé 14
Àwòrán: 1. Dáfídì dá àwọn ọmọ ogun rẹ̀ dúró nígbà tí wọ́n pàdé Ábígẹ́lì àtàwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tó kó oúnjẹ wá. 2. Ábígẹ́lì kúnlẹ̀ níwájú Dáfídì, ó sì ń bẹ̀ ẹ́.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ṣé O Máa Ń Hùwà Láìronú?

Ohun tí Dáfídì béèrè lọ́wọ́ Nábálì ò pọ̀ jù, àmọ́ Nábálì sọ̀rọ̀ burúkú sí i (1Sa 25:7-11; ia 78-79 ¶10-12)

Dáfídì pinnu láti pa gbogbo àwọn ọkùnrin tó wà nílé Nábálì (1Sa 25:13, 21, 22)

Ábígẹ́lì kò jẹ́ kí Dáfídì jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ (1Sa 25:25, 26, 32, 33; ia 80 ¶18)

BI ARA RẸ PÉ: ‘Ṣé mo máa ń hùwà láìronú tí inú bá ń bí mi tàbí tí mo bá rẹ̀wẹ̀sì? Ṣé mo máa ń ra nǹkan tó bá ṣáà ti wù mí? Àbí mo máa ń simẹ̀dọ̀, kí n sì fara balẹ̀ ro ìgbẹ̀yìn ọ̀rọ̀ kí n tó gbé ìgbésẹ̀?’​—Owe 15:28; 22:3.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́