ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Máa Sọ Gbogbo Ohun Tó Wà Lọ́kàn Ẹ fún Jèhófà
[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sámúẹ́lì Kìíní.]
Hánà gbàdúrà sí Jèhófà fún àkókò gígùn (1Sa 1:10, 12, 15; ia 55 ¶12)
Hánà fi ìṣòro ẹ̀ sílẹ̀ sọ́wọ́ Jèhófà (1Sa 1:18; w07 3/15 16 ¶3)
Tá a bá sọ gbogbo ohun tó wà lọ́kàn wa fún Jèhófà, ó dájú pé ó máa fún wa lókun, á sì ràn wá lọ́wọ́.—Sm 55:22; 62:8.