March Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, March-April 2022 March 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Téèyàn Bá Kọjá Àyè Ẹ̀, Ó Máa Kan Àbùkù March 14-20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ìgbọràn Sàn Ju Ẹbọ Lọ March 21-27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Ogun Náà Jẹ́ Ti Jèhófà” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ọ̀nà Mẹ́ta Tá A Lè Gbà Fi Hàn Pé A Gbára Lé Jèhófà March 28–April 3 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jẹ́ Onírẹ̀lẹ̀ Tó O Bá Ṣàṣeyọrí TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Jáwọ́ Nínú Ìwà Àìmọ́ April 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àwọn Wo Lò Ń Bá Ṣọ̀rẹ́ Lórí Ìkànnì? Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Bíbélì Kíkà Tó Wà fún Ìrántí Ikú Kristi Ti Ọdún 2022 April 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Bópẹ́bóyá, Kò Sí Ìṣòro Tí Ò Ní Dópin April 25–May 1 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ṣé O Máa Ń Hùwà Láìronú? TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ | JẸ́ KÍ IṢẸ́ SÍSỌNI DI ỌMỌ Ẹ̀YÌN MÁA FÚN Ẹ LÁYỌ̀ Ran Àwọn Tó Ò Ń Kọ́ Lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Lọ́wọ́ Láti Ní Àjọṣe Tímọ́tímọ́ Pẹ̀lú Jèhófà MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ