ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 September ojú ìwé 2
  • Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ó Gbèjà Àwọn Èèyàn Ọlọ́run
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
  • Ó Lo Ọgbọ́n àti Ìgboyà, Kò sì Mọ Tara Rẹ̀ Nìkan
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
  • Ó Lo Ọgbọ́n àti Ìgboyà, Ó sì Yọ̀ǹda Ara Rẹ̀ Tinútinú
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 September ojú ìwé 2
Ẹ́sítà ò jókòó ti àwọn ọmọbìnrin tó kù. Ó ń wo àwọn ẹyẹ tó ń ṣeré níbi omi, àmọ́ àwọn obìnrin tó kù gbájú mọ́ bí wọ́n ṣe fẹ́ ṣe ara wọn lóge. Ẹni tó ń tọ́jú wọn ń wo gbogbo wọn.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Mọ̀wọ̀n Ara Rẹ Bíi Ti Ẹ́sítà

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́sítà.]

Ẹ́sítà rẹwà gan-an (Ẹst 2:7)

Ẹ́sítà mọ̀wọ̀n ara ẹ̀ bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn èèyàn ń yìn ín, wọ́n sì ń pọ́n ọn ju bó ṣe yẹ lọ (Ẹst 2:​9, 15; w17.01 25 ¶11; ia 130 ¶15)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé ọ̀rọ̀ ẹnu mi àti ìwà mi fi hàn pé mo mọ̀wọ̀n ara mi àbí mo máa ń ka ara mi sí ju bó ṣe yẹ lọ?’—w17.01 25 ¶12.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́