ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Jẹ́ Kí Jèhófà Tù Ẹ́ Nínú
Ẹ̀rù ba Èlíjà, torí náà ó sá lọ (1Ọb 19:3, 4; w19.06 15 ¶5)
Jèhófà pèsè ohun tí Èlíjà nílò, ó sì fi agbára ńlá rẹ̀ han Èlíjà lọ́nà tó kàmàmà (1Ọb 19:5-7, 11, 12; ia 103 ¶13; 106 ¶21)
Jèhófà fún ní iṣẹ́ láti ṣe (1Ọb 19:15-18; ia 106 ¶22)
Lónìí, Jèhófà máa ń fi Bíbélì Ọ̀rọ̀ rẹ̀ bá wa sọ̀rọ̀. Bíbélì máa ń rán wa létí pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ wa dénu àti pé ó fún wa níṣẹ́ pàtàkì láti ṣe lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn rẹ̀.—1Kọ 15:58; Kol 3:23.