ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 September ojú ìwé 9
  • “Ìgbà Wo Lẹ Máa Ṣiyèméjì Dà?”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Ìgbà Wo Lẹ Máa Ṣiyèméjì Dà?”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jẹ́ Kí Jèhófà Tù Ẹ́ Nínú
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • B8 Tẹ́ńpìlì Tí Sólómọ́nì Kọ́
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • Bó O Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Èèyàn Sọ̀rọ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ó Gbèjà Ìjọsìn Mímọ́
    Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 September ojú ìwé 9
Èlíjà, àwọn wòlíì Báálì àtàwọn míì ń wo bí iná láti ọ̀run ṣe jó ẹbọ sísun tó wà lórí pẹpẹ.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ìgbà Wo Lẹ Máa Ṣiyèméjì Dà?”

Èlíjà ní káwọn ọmọ Ísírẹ́lì pinnu bóyá Jèhófà ni wọ́n máa jọ́sìn tàbí Báálì (1Ọb 18:21; w17.03 14 ¶6)

Òrìṣà tí kò lẹ́mìí ni Báálì (1Ọb 18:25-29; ia 88 ¶15)

Jèhófà fi hàn lọ́nà tó ṣàrà ọ̀tọ̀ pé òun nìkan ni Ọlọ́run tòótọ́ (1Ọb 18:36-38; ia 90 ¶18)

Èlíjà sọ fáwọn èèyàn náà pé tí wọ́n bá ń pa Òfin Jèhófà mọ́, ìyẹn á fi hàn pé wọ́n nígbàgbọ́. (Di 13:5-10; 1Ọb 18:40) Lónìí, a lè fi hàn pé a nígbàgbọ́, a sì bẹ̀rù Ọlọ́run tá a bá ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́