ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 July ojú ìwé 4
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Iṣẹ́ Ìsìn Àwọn Ọmọ Léfì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Bí Jèhófà Ṣe Fẹ́ Ká Máa Sin Òun
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Téèyàn Bá Rú Òfin Ọlọ́run, Àbájáde Ẹ̀ Kì Í Dáa
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 July ojú ìwé 4
Àwòrán: 1. Ọ̀gá kan ń dá ẹrú ẹ̀ tó jẹ́ ọmọ Ísírẹ́lì sílẹ̀. 2. Ọkùnrin kan ń fún ẹnì kan ní àkájọ ìwé tí wọ́n fi èdìdì dì.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń ran àwọn aláìní lọ́wọ́ àtàwọn tí kò ní ogún kankan (Di 14:28, 29; it-2 1110 ¶3)

Lọ́dún Sábáàtì, ọmọ Ísírẹ́lì tó bá jẹ gbèsè máa rí “ìtúsílẹ̀” gbà (Di 15:1-3; it-2 833)

Tọ́mọ Ísírẹ́lì kan bá ta ara ẹ̀ sóko ẹrú, ọ̀gá ẹ̀ gbọ́dọ̀ tú u sílẹ̀ lọ́dún keje, á sì tún fún un lẹ́bùn (Di 15:12-14; it-2 978 ¶6)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Kí ni mo lè ṣe láti fi hàn pé mo nífẹ̀ẹ́ àwọn ará tó jẹ́ aláìní?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́