ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 14
  • Iṣẹ́ Ìsìn Àwọn Ọmọ Léfì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Iṣẹ́ Ìsìn Àwọn Ọmọ Léfì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bí Wọ́n Ṣe Ń Jọ́sìn Nínú Tẹ́ńpìlì Túbọ̀ Wà Létòlétò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • “Èmi Ni . . . Ogún Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jèhófà Ni Ìpín Mi
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 14
Àwòrán: Àwọn ọmọ Léfì ń ṣe oríṣiríṣi iṣẹ́. 1. Ọmọ Léfì kan ń da omi sínú bàsíà bàbà. 2. Ọmọ Léfì kan ń fi kẹ̀kẹ́ kó ìkòkò. 3. Ọmọ Léfì kan gbé ìkòkò sí èjìká rẹ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Iṣẹ́ Ìsìn Àwọn Ọmọ Léfì

Jèhófà yan ẹ̀yà Léfì láti rọ́pò àkọ́bí ọkùnrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì (Nọ 3:11-13; it-2 683 ¶3)

Iṣẹ́ ìsìn tó ṣeyebíye làwọn ọmọ Léfì ń ṣe (Nọ 3:25, 26, 31, 36, 37; it-2 241)

Àwọn ọmọ Léfì tó wà láàárín ẹni ọgbọ̀n (30) ọdún sí àádọ́ta (50) ni wọ́n máa ń yàn láti ṣiṣẹ́ (Nọ 4:46-48; it-2 241)

Àwọn ọkùnrin tó jẹ́ àtọmọdọ́mọ Áárónì nìkan ló ń ṣiṣẹ́ àlùfáà, àwọn ọmọ Léfì tó kù sì máa ń ràn wọ́n lọ́wọ́. Bó ṣe rí nínú ìjọ lónìí nìyẹn, àwọn arákùnrin tó ń múpò iwájú lẹ́nu iṣẹ́ ìsìn Jèhófà ń ṣiṣẹ́ kára gan-an, àwọn arákùnrin tó kù sì ń ràn wọ́n lọ́wọ́.

Ọ̀dọ́kùnrin kan ń ṣàyẹ̀wò ohun tí ètò Ọlọ́run fi ránṣẹ́ sí ìjọ wọn. Arákùnrin kan kíyè sí ọ̀dọ́kùnrin náà, ó sì rẹ́rìn-ín múṣẹ́.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́