ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 2
  • Bí Wọ́n Ṣe Ń Jọ́sìn Nínú Tẹ́ńpìlì Túbọ̀ Wà Létòlétò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bí Wọ́n Ṣe Ń Jọ́sìn Nínú Tẹ́ńpìlì Túbọ̀ Wà Létòlétò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Iṣẹ́ Ìsìn Àwọn Ọmọ Léfì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Bí Jèhófà Ṣe Ṣètò Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bí Wọ́n Ṣe Ń Jọ́sìn Nínú Tẹ́ńpìlì Túbọ̀ Wà Létòlétò

Ọba Dáfídì ṣètò àwọn ọmọ Léfì àtàwọn àlùfáà kí wọ́n lè máa ṣiṣẹ́ ìsìn nínú tẹ́ńpìlì (1Kr 23:6, 27, 28; 24:1, 3; it-2 241, 686)

Wọ́n yan àwọn ọ̀jáfáfá àtàwọn akẹ́kọ̀ọ́ kí wọ́n lè máa kọrin ìyìn sí Jèhófà (1Kr 25:1, 8; it-2 451-452)

Wọ́n yan àwọn ọmọ Léfì kan láti máa bójú tó àwọn ibi ìṣúra, àwọn míì jẹ́ aṣọ́bodè, àwọn míì sì ń ṣe àwọn iṣẹ́ pàtàkì míì (1Kr 26:16-20; it-1 898)

Àwọn ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin nínú ilé ìpàdé kí ìpàdé tó bẹ̀rẹ̀. 1. Wọ́n ń kí ara wọn, wọ́n sì jọ ń sọ̀rọ̀. 2. Arákùnrin kan ń fi ohun tó wà lójú pátákó ìsọfúnni han arábìnrin kan. 3. Arábìnrin kan ń fi owó sínú àpótí ọrẹ. 4. Arákùnrin tó wà nídìí ìwé ń fún arábìnrin kan ní ìwé. 5. Arákùnrin kan ń tún makirofóònù tó wà lórí pèpéle ṣe. 6. Arákùnrin kan àti ọmọ ẹ̀ ń gbálẹ̀.

Bá a ṣe wà létòlétò fi hàn pé Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run ètò.​—1Kọ 14:33.

ṢE ÀṢÀRÒ: Báwo ni ìjọ Kristẹni òde òní ṣe ń jọ́sìn Jèhófà létòlétò?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́