ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 2
  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Bí Jèhófà Ṣe Ṣètò Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Bí Jèhófà Ṣe Ṣètò Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jèhófà Jà Fáwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • San Ẹ̀jẹ́ Rẹ
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Iṣẹ́ Ìsìn Àwọn Ọmọ Léfì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Bí Jèhófà Ṣe Ṣètò Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì

Àwọn tí Jèhófà yàn láti jẹ́ olórí ló máa ń múpò iwájú nínú ìjọsìn (Nọ 7:10; it-1 497 ¶3)

Àwọn ìránṣẹ́ Jèhófà gbọ́dọ̀ wà létòlétò (Nọ 7:11; it-2 796 ¶1)

Jèhófà kì í béèrè ohun tó ju agbára ẹnì kọ̀ọ̀kan lọ (Nọ 8:​25, 26; w04 8/1 25 ¶1)

Bí Jèhófà ṣe ṣètò àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nígbà àtijọ́, bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe ṣètò àwa èèyàn rẹ̀ lónìí. Àmọ́, ó ń kíyè sí ẹnì kọ̀ọ̀kan wa, ó ń rí gbogbo bá a ṣe ń sapá ká lè máa ṣe ìfẹ́ rẹ̀.

Àwòrán: Àwọn tí Jèhófà yàn ń múpò iwájú nínú ìjọ. 1. Alàgbà àti ọ̀dọ́kùnrin kan ń nu àwọn àga inú Gbọ̀ngàn Ìjọba. 2. Alàgbà kan ń kó àwọn ará jáde. 3. Alàgbà kan ń gbàdúrà ní ìpàdé àwọn alàgbà.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́