ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 3
  • Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Èmi Ni . . . Ogún Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Bí Jèhófà Ṣe Ṣètò Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Má Ṣe Máa Gbéra Ga, Má sì Dá Ara Rẹ Lójú Jù
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • “Ẹ Lé Gbogbo Àwọn Tó Ń Gbé Ilẹ̀ Náà Kúrò”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 3
Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí wà nínú yàrá ìgbohùnsílẹ̀, ó ń darí ètò Tẹlifíṣọ̀n JW.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀

Jèhófà ló máa ń pinnu ibi tó yẹ káwọn èèyàn rẹ̀ lọ àti ìgbà tó yẹ kí wọ́n gbéra (Nọ 9:​17, 18; it-1 398 ¶3)

Ẹsẹ̀kẹsẹ̀ làwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ìtọ́ni Jèhófà (Nọ 9:​21, 22; w11 4/15 4-5)

Àwọn èèyàn aláìpé ni Jèhófà máa ń lò láti fún àwọn èèyàn rẹ̀ ní ìtọ́ni (Nọ 10:​5-8)

Tá a bá ń ṣègbọràn sáwọn tí Jèhófà ń lò láti darí wa, Jèhófà là ń ṣègbọràn sí.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́