ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 March ojú ìwé 8
  • Má Ṣe Máa Gbéra Ga, Má sì Dá Ara Rẹ Lójú Jù

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Má Ṣe Máa Gbéra Ga, Má sì Dá Ara Rẹ Lójú Jù
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Èmi Ni . . . Ogún Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Bí Jèhófà Ṣe Ń Darí Àwọn Èèyàn Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ṣé Jèhófà Mọ̀ Ẹ́?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Máa Wádìí Lọ́dọ̀ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 March ojú ìwé 8
Àwọn kan lára àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì wà lẹ́yìn Kórà bó ṣe ń ta ko Mósè àti Ààrónì.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Má Ṣe Máa Gbéra Ga, Má sì Dá Ara Rẹ Lójú Jù

Kórà di agbéraga, ó sì dá ara ẹ̀ lójú jù, torí náà kò fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ètò tí Jèhófà ṣe (Nọ 16:​1-3; w11 9/15 27 ¶12)

Ọmọ Léfì táwọn èèyàn bọ̀wọ̀ fún ni Kórà, ọ̀pọ̀ àǹfààní iṣẹ́ ìsìn ló sì ní (Nọ 16:​8-10; w11 9/15 27 ¶11)

Kórà gba èròkerò láyè, ohun tó sì tẹ̀yìn ẹ̀ yọ ò dáa rárá (Nọ 16:​32, 35)

A ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí àwọn àṣeyọrí tá a ṣe lẹ́nu iṣẹ́ Jèhófà mú ká di agbéraga tàbí ká máa dá ara wa lójú jù. Bá a bá ṣe ń pẹ́ sí i nínú òtítọ́ tàbí bí iṣẹ́ tá à ń bójú tó nínú ètò Ọlọ́run bá ṣe ń pọ̀ sí i, bẹ́ẹ̀ náà ló ṣe yẹ ká túbọ̀ máa jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ sí i.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́