ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 January ojú ìwé 4
  • Máa Wádìí Lọ́dọ̀ Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Wádìí Lọ́dọ̀ Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Èmi Ni . . . Ogún Rẹ”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ó Nígboyà, Ó sì Fìtara Jíṣẹ́ Tí Jèhófà Rán An Láìfi Falẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ohun Táwọn Òbí Lè Rí Kọ́ Látinú Ohun Tí Mánóà àti Ìyàwó Rẹ̀ Ṣe
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Má Ṣe Máa Gbéra Ga, Má sì Dá Ara Rẹ Lójú Jù
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 January ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Wádìí Lọ́dọ̀ Jèhófà

Léraléra làwọn ọmọ Ísírẹ́lì bẹ Jèhófà pé kó tọ́ àwọn sọ́nà (Ond 20:17, 18, 23; w11 9/15 32 ¶2)

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbára lé Jèhófà pátápátá kó lè ràn wọ́n lọ́wọ́ láti mú ẹ̀gàn tí wọ́n kó bá orúkọ rẹ̀ kúrò (Ond 20:26-28)

A ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kó sú wa láti máa wá ìtọ́sọ́nà Jèhófà ká sì gbára lé e pátápátá (Ond 20:35; Lk 11:9; w11 9/15 32 ¶4)

Àwòrán: 1. Arákùnrin kan ń ṣèwádìí nínú Bíbélì àtàwọn ìtẹ̀jáde wa. 2. Arákùnrin náà ń bá dọ́kítà sọ̀rọ̀, ó sì fi káàdì ìtọ́jú ìṣègùn rẹ̀ hàn án.

BI ARA Ẹ PÉ: ‘Ṣé ọ̀dọ̀ Jèhófà ni mo máa ń yíjú sí lẹsẹ̀kẹsẹ̀ tí ìṣòro bá yọjú? Ṣé mo máa ń bẹ̀ ẹ́ léraléra láti fún mi ní ọgbọ́n, kó sì tọ́ mi sọ́nà?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́