ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 14
  • Ohun Táwọn Òbí Lè Rí Kọ́ Látinú Ohun Tí Mánóà àti Ìyàwó Rẹ̀ Ṣe

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ohun Táwọn Òbí Lè Rí Kọ́ Látinú Ohun Tí Mánóà àti Ìyàwó Rẹ̀ Ṣe
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Lọ Lo Agbára Tí O Ní”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Máa Wádìí Lọ́dọ̀ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí Sí Rere
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 14
Àwọn òbí yìí ń lo ìwé “Kẹ́kọ̀ọ́ Lọ́dọ̀ Olùkọ́ Ńlá Náà” láti kọ́ àwọn ọmọ wọn.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ohun Táwọn Òbí Lè Rí Kọ́ Látinú Ohun Tí Mánóà àti Ìyàwó Rẹ̀ Ṣe

Ẹ jẹ́ kó máa hàn nínú ìwà yín pé ẹ ní àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Jèhófà (Ond 13:1, 2, 6)

Ẹ jẹ́ kí Jèhófà máa darí gbogbo nǹkan tẹ́ ẹ bá ń ṣe (Ond 13:8; w13 8/15 16 ¶1)

Ẹ máa bá àwọn ọmọ yín wí nígbà tó bá yẹ (Ond 14:1-4; w05 3/15 25 ¶5)

Oríṣiríṣi ìwé àtàwọn fídíò táwọn òbí lè lò láti kọ́ àwọn ọmọ wọn.

Àwọn ìtẹ̀jáde wo ló wà lédè yín táwọn òbí lè lò láti kọ́ àwọn ọmọ wọn?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́