ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 10
  • “Lọ Lo Agbára Tí O Ní”

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • “Lọ Lo Agbára Tí O Ní”
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • “Idà Jèhófà Àti Ti Gídíónì!”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • Ẹ̀yin Alàgbà, Ẹ Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Gídíónì
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2023
  • Gídíónì Àti Ọ̀ọ́dúnrún Ọkùnrin Rẹ̀
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Ó Sàn Kéèyàn Lẹ́mìí Ìrẹ̀lẹ̀ Ju Kó Jẹ́ Agbéraga
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 10
Gídíónì àtàwọn ọkùnrin rẹ̀ mú ògùṣọ̀ àti ìwo dání, wọ́n sì ń kígbe.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Lọ Lo Agbára Tí O Ní”

Jèhófà ní kí Gídíónì ṣe iṣẹ́ kan tó nira láti ṣe (Ond 6:2-6, 14)

Gídíónì gbà pé òun ò já mọ́ nǹkan kan àti pé iṣẹ́ náà ò tọ́ sóun (Ond 6:15; w02 2/15 6 ¶5)

Jèhófà ran Gídíónì lọ́wọ́ kó lè ṣàṣeyọrí lẹ́nu iṣẹ́ náà (Ond 7:19-22; w05 7/15 16 ¶3)

Àwọn arákùnrin méjì fẹ́ wàásù fún obìnrin kan. Ọ̀kan nínú àwọn arákùnrin náà jókòó sórí kẹ̀kẹ́ arọ, ẹnìkejì sì ń tì í.

Jèhófà fẹ́ ká fi gbogbo okun wa jọ́sìn òun. Tó bá ń ṣe wá bíi pé a ò lókun mọ́, ẹ̀mí mímọ́ Jèhófà máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè ṣàṣeyọrí.​—Ais 40:30, 31.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́