ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 November ojú ìwé 12
  • Ó Sàn Kéèyàn Lẹ́mìí Ìrẹ̀lẹ̀ Ju Kó Jẹ́ Agbéraga

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ó Sàn Kéèyàn Lẹ́mìí Ìrẹ̀lẹ̀ Ju Kó Jẹ́ Agbéraga
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Eeṣe Ti A Fi Nilati Gbé Irẹlẹ Wọ̀?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1991
  • “Lọ Lo Agbára Tí O Ní”
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ní Ojúlówó Ẹ̀mí Ìrẹ̀lẹ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2005
  • “Ẹni Rírẹlẹ̀ ní Ọkàn-Àyà Ni Èmi”
    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn”
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 November ojú ìwé 12

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ó Sàn Kéèyàn Lẹ́mìí Ìrẹ̀lẹ̀ Ju Kó Jẹ́ Agbéraga

Onírẹ̀lẹ̀ ni Gídíónì, torí náà ó ṣe gbogbo ohun tó lè ṣe kó lè wá àlàáfíà (Ond 8:1-3; w00 8/15 25 ¶3)

Torí pé Gídíónì lẹ́mìí ìrẹ̀lẹ̀, kò gba ògo tó tọ́ sí Jèhófà (Ond 8:22, 23; w17.01 20 ¶15)

Torí pé Ábímélékì jẹ́ agbéraga, ó pàdánù ẹ̀mí ẹ̀, ó sì kó àwọn míì sí wàhálà (Ond 9:1, 2, 5, 22-24; w08 2/15 9 ¶9)

Inú ń bí onílé kan, ó sì jágbé mọ tọkọtaya tó fẹ́ wàásù fún un.

Báwo ni ẹ̀mí ìrẹ̀lẹ̀ ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ tá a bá pàdé ẹnì kan tínú ń bí lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́