ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 September ojú ìwé 4
  • Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí Sí Rere

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí Sí Rere
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Nígbàgbọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Yẹra fún Ojúsàájú, Kó O Lè Fìwà Jọ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Máa Fún Àwọn Míì Níṣìírí Nígbà Ìṣòro
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ìmọ́lẹ̀ Ń Mọ́lẹ̀ Sí I
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 September ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí Sí Rere

[Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jóṣúà.]

Máa kẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, kó o sì máa fi ohun tó ò ń kọ́ sílò (Joṣ 1:7, 8; w13 1/15 8 ¶7)

Jẹ́ kó dá ẹ lójú pé Jèhófà á ràn ẹ́ lọ́wọ́ bó o ṣe ń ṣe ohun tó tọ́ (Joṣ 1:9; w13 1/15 11 ¶20)

Àwòrán: 1. Arákùnrin kan ń wàásù fún ẹni tí wọ́n jọ ń ṣiṣẹ́ lásìkò oúnjẹ ọ̀sán. 2. Arákùnrin kan jẹ́ adúróṣinṣin nígbà táwọn ọlọ́pàá ń halẹ̀ mọ́ ọn.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àwọn nǹkan wo ló lè ṣẹlẹ̀ tá gba pé kí n jẹ́ onígboyà?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́