ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 September ojú ìwé 6
  • Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Nígbàgbọ́

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Nígbàgbọ́
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí Sí Rere
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Yẹra fún Ojúsàájú, Kó O Lè Fìwà Jọ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Máa Fún Àwọn Míì Níṣìírí Nígbà Ìṣòro
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ìmọ́lẹ̀ Ń Mọ́lẹ̀ Sí I
    Ìwé Ọdọọdún Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà—2016
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 September ojú ìwé 6
Àwọn àlùfáà gbé àpótí májẹ̀mú bí wọ́n ṣe ń lọ sínú Odò Jọ́dánì lásìkò tó ń yára ṣàn.

Àwọn àlùfáà gbé àpótí májẹ̀mú bí wọ́n ṣe ń lọ sínú Odò Jọ́dánì

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Nígbàgbọ́

Ó lè dà bíi pé àwọn ìtọ́ni Jèhófà ò bọ́gbọ́n mu nígbà míì (Joṣ 3:12, 13; it-2 105; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ó yẹ káwọn alábòójútó máa múpò iwájú tó bá dọ̀rọ̀ ká tẹ̀ lé ìtọ́ni (Joṣ 3:14; w13 9/15 16 ¶17)

Jèhófà máa ń bù kún àwọn tó bá pinnu láti ṣe ohun tó tọ́ (Joṣ 3:15-17; w13 9/15 16 ¶18)

Àwọn àlùfáà gbé àpótí májẹ̀mú bí wọ́n ṣe ń gba orí ilẹ̀ gbígbẹ kọjá láàárín Odò Jọ́dánì.

Jèhófà máa bù kún wa tá a bá ṣe gbogbo ohun tá a lè ṣe láti wàásù, kódà tí ìlera wa tàbí ipò tá a wà ò bá jẹ́ ká lè ṣe tó bá a ṣe fẹ́.

Arábìnrin kan ń wàásù fún obìnrin kan níbi ìgbafẹ́ lórílẹ̀-èdè tí ìjọba ti fòfin de iṣé wa, ọlọ́pàá sì ń kọjá lẹ́yìn wọn.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́