ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 May ojú ìwé 2
  • Yẹra fún Ojúsàájú, Kó O Lè Fìwà Jọ Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Yẹra fún Ojúsàájú, Kó O Lè Fìwà Jọ Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bó O Ṣe Lè Mú Kí Ọ̀nà Rẹ Yọrí Sí Rere
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jèhófà Máa Ń Bù Kún Àwọn Tó Nígbàgbọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Máa Fún Àwọn Míì Níṣìírí Nígbà Ìṣòro
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ìwọ́ Ha Ń fara Wé Ọlọ́run Wa Tí Kì í Ṣojúsàájú Bí?
    Ilé-Ìṣọ́nà Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1996
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 May ojú ìwé 2
Àwọn ọmọbìnrin Sélóféhádì márààrún ń sọ ẹ̀dùn ọkàn wọn fún Mósè lẹ́nu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé.

Àwọn ọmọbìnrin Sélóféhádì béèrè fún ogún bàbá wọn

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Yẹra fún Ojúsàájú, Kó O Lè Fìwà Jọ Jèhófà

Àwọn ọmọbìnrin Sélóféhádì márùn-ún fẹ́ gba ogún bàbá wọn (Nọ 27:​1-4; w13 6/15 10 ¶14; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ìpinnu tí Jèhófà ṣe fi hàn pé kì í ṣe ojúsàájú (Nọ 27:5-7; w13 6/15 11 ¶15)

Àwa náà gbọ́dọ̀ yẹra fún ojúsàájú (Nọ 27:8-11; w13 6/15 11 ¶16)

Tá a bá ń fìfẹ́ hàn sáwọn ará wa, tá à ń bọ̀wọ̀ fún wọn, tá a sì ń wàásù fún onírúurú èèyàn láìka ibi tí wọ́n ti wá sí, ṣe là ń fi hàn pé a kì í ṣe ojúsàájú, àá sì máa fìwà jọ Jèhófà.

Àwòrán: Bá a ṣe lè fi hàn pé a kì í ṣe ojúsàájú. 1. Àwọn ọ̀rẹ́ márùn-ún tí ọjọ́ orí wọn àti ẹ̀yà wọn yàtọ̀ síra jọ ń jẹun, wọ́n sì ń gbádùn ara wọn. 2. Tọkọtaya kan ń wàásù fún ọkùnrin kan tí ẹ̀yà ẹ̀ yàtọ̀ sí tiwọn ní ibùdó àwọn tó ń wá ibi ìsádi.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́