ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 May ojú ìwé 12
  • Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Ṣe Ohun Tí Jèhófà Fẹ́ Nígbà Gbogbo
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ohun Táwọn Òbí Lè Rí Kọ́ Látinú Ohun Tí Mánóà àti Ìyàwó Rẹ̀ Ṣe
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ọgbọ́n Táwọn Alátakò Máa Ń Dá Kí Wọ́n Lè Kó Ìrẹ̀wẹ̀sì Bá Wa
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àwọn Òfin Jèhófà Bọ́gbọ́n Mu, Wọ́n sì Bá Ìdájọ́ Òdodo Mu
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 May ojú ìwé 12

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Kọ́ Ọmọ Rẹ Kó Lè Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà

Àwọn òbí gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà (Di 6:5; w05 6/15 20 ¶11)

Wọ́n gbọ́dọ̀ fi àpẹẹrẹ tó dáa lélẹ̀ fáwọn ọmọ wọn (Di 6:6; w07 5/15 15-16)

Wọ́n gbọ́dọ̀ máa kọ́ àwọn ọmọ nípa Jèhófà léraléra (Di 6:7; w05 6/15 21 ¶14)

Yàtọ̀ sígbà tẹ́ ẹ bá ń ṣe ìjọsìn ìdílé, àwọn ìgbà wo lo tún lè kọ́ àwọn ọmọ rẹ kí wọ́n lè nífẹ̀ẹ́ Jèhófà àtàwọn ìlànà rẹ̀?

Bàbá kan àti ọmọkùnrin ẹ̀ jọ ń ṣe káìtì. Àwòrán ẹyẹ látinú àpilẹ̀kọ ‘Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí?’ wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ wọn.
Bàbá yẹn ń bá ọmọbìnrin ẹ̀ sọ̀rọ̀ bí ọmọ náà ṣe ń kun àwòrán igi ápù. Bàbá náà sì ń nawọ́ sí èso ápù tó wà níwájú wọn.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́