ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 May ojú ìwé 10
  • Àwọn Òfin Jèhófà Bọ́gbọ́n Mu, Wọ́n sì Bá Ìdájọ́ Òdodo Mu

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Òfin Jèhófà Bọ́gbọ́n Mu, Wọ́n sì Bá Ìdájọ́ Òdodo Mu
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ọbabìnrin Ṣébà Mọyì Kéèyàn Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Máa Yin Jèhófà Nítorí Ọgbọ́n Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 May ojú ìwé 10

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Àwọn Òfin Jèhófà Bọ́gbọ́n Mu, Wọ́n sì Bá Ìdájọ́ Òdodo Mu

A máa fi hàn pé a jẹ́ ọlọ́gbọ́n àti olóye tá a bá ń pa òfin Ọlọ́run mọ́ (Di 4:6; it-2 1140 ¶5)

Ọ̀pọ̀ àwọn tó ń kíyè sí ìwà wa ló gbà pé ó bọ́gbọ́n mu láti máa pa àwọn òfin Ọlọ́run mọ́ lóòótọ́ (Di 4:6; w99 11/1 20 ¶6-7)

Ìgbésí ayé àwa èèyàn Jèhófà máa ń dáa gan-an ju tàwọn èèyàn ayé lọ (Di 4:7, 8; w07 8/1 29 ¶13)

Ìwà wa dáa torí pé à ń tẹ̀ lé àwọn òfin àti ìlànà Jèhófà, ìyẹn sì ti mú kí ọ̀pọ̀ èèyàn wá sínú ètò Jèhófà.

Arákùnrin tó wà nídìí ìpàtẹ ìwé rí i tí pọ́ọ̀sì ọkùnrin kan ń já bọ́ lápò rẹ̀, obìnrin kan sì ń wò ohun tó ń ṣẹlẹ̀ níbi tó jókòó sí.
Arákùnrin yìí ń fún ọkùnrin náà ní pọ́ọ̀sì yẹn, obìnrin náà ṣì ń wò wọ́n níbi tó jókòó sí.

Àwọn ìbùkún wo lo ti rí torí pé ò ń tẹ̀ lé àwọn ìlànà Jèhófà?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́