ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 September ojú ìwé 2
  • Máa Yin Jèhófà Nítorí Ọgbọ́n Rẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Máa Yin Jèhófà Nítorí Ọgbọ́n Rẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ọbabìnrin Ṣébà Mọyì Kéèyàn Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Ìbẹ̀wò Kan Tó Lérè Púpọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
  • Sólómọ́nì Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gbàdúrà Látọkàn Wá
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Bí Ọgbọ́n Ṣe Ṣeyebíye Tó
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 September ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Máa Yin Jèhófà Nítorí Ọgbọ́n Rẹ̀

Jèhófà fún Sólómọ́nì ní ọgbọ́n tó ṣàrà ọ̀tọ̀ (1Ọb 10:1-3; w99 7/1 30 ¶6)

Ẹnu ya ọbabìnrin Ṣébà nígbà tó rí ọgbọ́n tí Jèhófà fún Sólómọ́nì (1Ọb 10:4, 5; w99 11/1 20 ¶6)

Ọbabìnrin Ṣébà yin Jèhófà torí pé Sólómọ́nì ló yàn láti jẹ́ ọba (1Ọb 10:6-9; w99 7/1 30-31)

Arábìnrin kan ń wàásù fún obìnrin kan nílé oúnjẹ.

Bíi ti ọbabìnrin Ṣébà, a lè fi hàn pé a mọyì ọgbọ́n Jèhófà. Ọ̀nà wo la lè gbà ṣe bẹ́ẹ̀? Ọ̀nà kan tá a lè gbà ṣe bẹ́ẹ̀ ni pé ká máa fi ohun tí Jésù kọ́ni sílò, ká sì ṣe gbogbo ohun tá a bá lè ṣe láti máa fara wé e. (Mt 12:42; 1Pe 2:21) Ọ̀nà míì ni pé ká máa sọ nípa ọgbọ́n Ọlọ́run fáwọn míì lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́