ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 July ojú ìwé 10
  • Bí Ọgbọ́n Ṣe Ṣeyebíye Tó

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bí Ọgbọ́n Ṣe Ṣeyebíye Tó
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ṣé Ò Ń Jẹ́ Kí “Ọgbọ́n Tó Wá Láti Òkè” Darí Rẹ?
    Sún Mọ́ Jèhófà
  • Sólómọ́nì Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gbàdúrà Látọkàn Wá
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Wọ́n Fi Gbogbo Ọkàn sí Iṣẹ́ Ilé Náà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Sólómọ́nì Fọgbọ́n Ṣàkóso
    Kí Ló Wà Nínú Bíbélì?
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 July ojú ìwé 10
Sólómọ́nì ń gbọ́ ẹjọ́ àwọn aṣẹ́wó méjì tó ń jà sí ọmọ kan náà.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bí Ọgbọ́n Ṣe Ṣeyebíye Tó

Sólómọ́nì bẹ Jèhófà pé kó fún òun ní ọgbọ́n (1Ọb 3:7-9; w11 12/15 8 ¶4-6)

Inú Jèhófà dùn sí ohun tí Sólómọ́nì béèrè (1Ọb 3:10-13)

Torí pé Sólómọ́nì mọyì ọgbọ́n Ọlọ́run, àlàáfíà jọba ní ilẹ̀ náà (1Ọb 4:25)

Ẹni tó ní ọgbọ́n máa ń lo ìmọ̀ àti òye tó ní láti ṣe ìpinnu tó bọ́gbọ́n mu. Kódà, ó sàn kéèyàn ní ọgbọ́n ju kó ní wúrà lọ. (Owe 16:16) Tá a bá bẹ Ọlọ́run pé kó fún wa ní ọgbọ́n, tá à ń bẹ̀rù rẹ̀, tá a nírẹ̀lẹ̀, tá a mọ̀wọ̀n ara wa, tá a sì ń walẹ̀ jìn nínú Ọ̀rọ̀ rẹ̀, ó dájú pé a máa ní ọgbọ́n.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́