ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 July ojú ìwé 11
  • Wọ́n Fi Gbogbo Ọkàn sí Iṣẹ́ Ilé Náà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Wọ́n Fi Gbogbo Ọkàn sí Iṣẹ́ Ilé Náà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Bí Ọgbọ́n Ṣe Ṣeyebíye Tó
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Sólómọ́nì Kọ́ Tẹ́ńpìlì
    Ìwé Ìtàn Bíbélì
  • Sólómọ́nì Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gbàdúrà Látọkàn Wá
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Wọ́n Kọ́ Tẹ́ńpìlì fún Jèhófà
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 July ojú ìwé 11
Ọba Sólómọ́nì ń fetí sílẹ̀ bí ọ̀kan lára àwọn tó ń ṣiṣẹ́ níbi tí wọ́n ti ń kọ́ tẹ́ńpìlì ṣe ń ṣàlàyé bí iṣẹ́ náà ṣe ń lọ.

Ọba Sólómọ́nì ń wo bí iṣẹ́ ṣe ń lọ níbi tí wọ́n ti ń kọ́ tẹ́ńpìlì

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Wọ́n Fi Gbogbo Ọkàn sí Iṣẹ́ Ilé Náà

Àwọn ohun èlò ìkọ́lé tó dáa jù ni Sólómọ́nì fi kọ́ tẹ́ńpìlì náà (1Ọb 5:6, 17; w11 2/1 15)

Ọ̀pọ̀ èèyàn ló lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ náà (1Ọb 5:13-16; it-1 424; it-2 1077 ¶1)

Ọdún méje ni Sólómọ́nì àtàwọn èèyàn náà fi ṣiṣẹ́ kára kí wọ́n tó parí tẹ́ńpìlì náà (1Ọb 6:38; wo àwòrán iwájú ìwé)

Sólómọ́nì àtàwọn èèyàn náà kọ́ tẹ́ńpìlì tó rẹwà fún Jèhófà torí pé wọ́n nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, wọ́n sì fi gbogbo ọkàn sí iṣẹ́ náà. Àmọ́ ó bani nínú jẹ́ pé, bọ́dún ṣe ń gorí ọdún, àwọn àtọmọdọ́mọ wọn ò fọwọ́ pàtàkì mú ìjọsìn Jèhófà, wọn ò sì bójú tó tẹ́ńpìlì náà. Nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín, àwọn ọ̀tá pa tẹ́ńpìlì náà run.

Inú àwọn ará lọ́kùnrin àti lóbìnrin ń dùn bí wọ́n ṣe ń bójú tó ìmọ́tótó Gbọ̀ngàn Ìjọba. Lọ́wọ́ ẹ̀yìn, àwọn kan ń fi owó sínú àpótí ọrẹ, àwọn míì ń bá ara wọn sọ̀rọ̀, àwọn míì sì ń ṣètò ìwé táwọn ará máa lò.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Kí ni mò ń ṣe kí ìtara tí mo ní fún ìjọsìn Ọlọ́run má bàa jó rẹ̀yìn?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́