ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 March ojú ìwé 10
  • Ọbabìnrin Ṣébà Mọyì Kéèyàn Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọbabìnrin Ṣébà Mọyì Kéèyàn Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Máa Yin Jèhófà Nítorí Ọgbọ́n Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìbẹ̀wò Kan Tó Lérè Púpọ̀
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—1999
  • Àwọn Òfin Jèhófà Bọ́gbọ́n Mu, Wọ́n sì Bá Ìdájọ́ Òdodo Mu
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Sólómọ́nì Fi Ìrẹ̀lẹ̀ Gbàdúrà Látọkàn Wá
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 March ojú ìwé 10
Ọbabìnrin Ṣébà ń mú ẹ̀bùn lọ fún Ọba Sólómọ́nì. Ọba Sólómọ́nì dìde lọ pàdé ẹ̀. Àwọn akọrin àti àwọn ẹ̀ṣọ́ dúró sí ìsàlẹ̀ ibi àtẹ̀gùn tó lọ síbi ìtẹ́ Sólómọ́nì.

Ọbabìnrin Ṣébà ṣèbẹ̀wò sí ààfin Ọba Sólómọ́nì

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ọbabìnrin Ṣébà Mọyì Kéèyàn Jẹ́ Ọlọ́gbọ́n

Ọbabìnrin Ṣébà rin ìrìn àjò ọ̀nà tó jìn tó sì ń tánni lókun láti lọ rí Sólómọ́nì (2Kr 9:1, 2; w99 11/1 20 ¶4; w99 7/1 30 ¶4-5)

Nígbà tó rí ọgbọ́n àti ọrọ̀ Sólómọ́nì, ẹnu yà á gan-an (2Kr 9:3, 4; w99 7/1 30-31; wo àwòrán iwájú ìwé)

Ohun tó rí mú kó yin Jèhófà (2Kr 9:7, 8; it-2 990-991)

Ọbabìnrin Ṣébà àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wà lórí ràkúnmí, wọ́n ń rìnrìn-àjò lọ sọ́dọ̀ Ọba Sólómọ́nì.

Ọbabìnrin Ṣébà mọyì kéèyàn ní ọgbọ́n. Ìyẹn ló jẹ́ kó yááfì ọ̀pọ̀ nǹkan kó lè ní i. 

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mo ṣe tán láti wá ọgbọ́n bí ìgbà téèyàn ń wá àwọn ìṣúra tó fara sin?’​—Owe 2:1-6.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́