ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 November ojú ìwé 5
  • Ó Nígboyà, Ó sì Fìtara Jíṣẹ́ Tí Jèhófà Rán An Láìfi Falẹ̀

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ó Nígboyà, Ó sì Fìtara Jíṣẹ́ Tí Jèhófà Rán An Láìfi Falẹ̀
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jéhù Jà fún Ìjọsìn Mímọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2011
  • Ọlọ́run Fìyà Jẹ Ayaba Kan Tó Burú Gan-an
    Àwọn Ẹ̀kọ́ Tó O Lè Kọ́ Látinú Bíbélì
  • “Gbogbo Ilé Áhábù Ló Máa Ṣègbé”—2Ọb 9:8
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Máa Wádìí Lọ́dọ̀ Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 November ojú ìwé 5
Jéhù wà lórí kẹ̀kẹ́ ẹṣin, ó sì sọ fún ọ̀ṣìṣẹ́ kan pé kó ju Jésíbẹ́lì sílẹ̀ láti ojú wíńdò.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ó Nígboyà, Ó sì Fìtara Jíṣẹ́ Tí Jèhófà Rán An Láìfi Falẹ̀

Jèhófà sọ fún Jéhù pé kó lọ pa àwọn ará ilé Áhábù tó jẹ́ ọba búburú run (2Ọb 9:6, 7; w11 11/15 3 ¶2)

Jéhù gbé ìgbésẹ̀ láìjáfara, ó sì pa Ọba Jèhórámù (ìyẹn ọmọ Áhábù) àti Ayaba Jésíbẹ́lì (ìyẹn ìyàwó Áhábù) (2Ọb 9:22-24, 30-33; w11 11/15 4 ¶2-3; wo àtẹ náà “‘Gbogbo Ilé Áhábù Ló Máa Ṣègbé’​—2Ọb 9:8”)

Jéhù lo ìgboyà, ó sì fìtara jíṣẹ́ tí Jèhófà rán an láìfi falẹ̀ (2Ọb 10:17; w11 11/15 5 ¶3-4)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fara wé Jéhù tó bá di pé kí n tẹ̀ lé àṣe tó wà nínú Mátíù 28:19, 20?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́