November Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, November-December 2022 November 7-13 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wa Pọ̀ Ju Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wọn MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Ẹ Sọ Ọ́ Di Àṣà Láti Máa Fúnni” November 14-20 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Ṣe Ohun Tó Dà Bíi Pé Kò Ṣeé Ṣe November 21-27 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ó Nígboyà, Ó sì Fìtara Jíṣẹ́ Tí Jèhófà Rán An Láìfi Falẹ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ohun Tí Kò Ní Jẹ́ Ká Máa Fi Nǹkan Falẹ̀ November 28–December 4 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Fìyà Jẹ Obìnrin Burúkú Kan ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Gbogbo Ilé Áhábù Ló Máa Ṣègbé”—2Ọb 9:8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Káwa Kristẹni Máa Sapá Láti Tẹ̀ Síwájú? December 5-11 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Jèhófà Máa Ń Bù Kún Ìsapá Tá A Bá Fi Gbogbo Ọ̀kan Ṣe MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jèhófà Ò Ní Gbàgbé Iṣẹ́ Wa December 12-18 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Sùúrù Jèhófà Níbi Tó Mọ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Fọkàn Balẹ̀ Bí Ètò Àwọn Nǹkan Yìí Ṣe Ń Lọ Sópin December 19-25 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ọgbọ́n Táwọn Alátakò Máa Ń Dá Kí Wọ́n Lè Kó Ìrẹ̀wẹ̀sì Bá Wa MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ Máa Yọ̀ Tẹ́ Ẹ Bá Ń Dojú Kọ Inúnibíni December 26, 2022–January 1, 2023 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Àdúrà Mú Kí Jèhófà Gbé Ìgbésẹ̀ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Àdúrà Wa Ṣeyebíye Lójú Jèhófà MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ