ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 May ojú ìwé 3
  • San Ẹ̀jẹ́ Rẹ

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • San Ẹ̀jẹ́ Rẹ
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2002
  • “Ohun Tí O Jẹ́jẹ̀ẹ́, San Án”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2017
  • Àwọn Olóòótọ́ Ìránṣẹ́ Jèhófà Máa Ń San Ẹ̀jẹ́ Wọn
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2024
  • Ohun Tá A Rí Kọ́ Látinú Bí Jèhófà Ṣe Ṣètò Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 May ojú ìwé 3

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

San Ẹ̀jẹ́ Rẹ

Dandan kọ́ ni káwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ́jẹ̀ẹ́, àmọ́ tí wọ́n bá ṣe bẹ́ẹ̀, wọ́n gbọ́dọ̀ san ohun tí wọ́n jẹ́jẹ̀ẹ́ (Nọ 30:2; it-2 1162)

Ẹnì kan lè jẹ́jẹ̀ẹ́ pé òun ò ní ṣe ohun kan bó tiẹ̀ jẹ́ pé kò sófin tó ní kó má ṣe nǹkan náà (Nọ 30:​3, 4; it-2 1162)

Lóde òní, ẹnì kọ̀ọ̀kan ló máa pinnu ohun tóun fẹ́ ṣe láti múnú Jèhófà dùn (Nọ 30:​6-9; w04 8/1 27 ¶4)

Ẹ̀jẹ́ ìyàsímímọ́ àti ẹ̀jẹ́ ìgbéyàwó ni ẹ̀jẹ́ méjì tó ṣe pàtàkì jù lọ táwa Kristẹni máa ń jẹ́ lónìí.

Àwòrán: Àwọn tó ń jẹ́jẹ̀ẹ́. 1. Ọ̀dọ́bìnrin kan ń gbàdúrà. 2. Tọkọtaya tó ń fi òrùka sọ́wọ́ ara wọn lọ́jọ́ ìgbéyàwó wọn.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Ṣé mò ń mú ẹ̀jẹ́ mi ṣẹ?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́