ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb22 January ojú ìwé 3
  • Téèyàn Bá Rú Òfin Ọlọ́run, Àbájáde Ẹ̀ Kì Í Dáa

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Téèyàn Bá Rú Òfin Ọlọ́run, Àbájáde Ẹ̀ Kì Í Dáa
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹni Tẹ̀mí ni Jẹ́fútà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • A Óò Máa Rìn Ní Orúkọ Jèhófà Títí Láé!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
  • Àwọn Ìránṣẹ́ Jèhófà Ní Ìrètí Tòótọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2003
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
mwb22 January ojú ìwé 3

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Téèyàn Bá Rú Òfin Ọlọ́run, Àbájáde Ẹ̀ Kì Í Dáa

Míkà jí owó ìyá rẹ̀ (Ond 17:1, 2)

Míkà ṣe àwọn ère òrìṣà, kò sì tẹ̀ lé òfin tí Jèhófà ṣe nípa ìjọsìn (Ond 17:4, 5, 12; it-2 390-391)

Nígbẹ̀yìn-gbẹ́yín, Míkà pàdánù gbogbo ohun tó ní (Ond 18:24-26; it-2 391 ¶2)

Obìnrin kan tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí Jèhófà tẹ́lẹ̀ ti lọ́mọ báyìí, ó ń ronú nípa bí nǹkan ṣe rí fún òun nígbà tóun ṣì ń sin Jèhófà. Sìgá wà lórí tábílì tó wà níwájú ẹ̀. Ọkùnrin kan tó ti mutí yó sì sùn sórí àga.

BI ARA RẸ PÉ, ‘Àǹfààní wo ni mo ti rí bí mo ṣe ń pa òfin Jèhófà mọ́?’

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́