ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Ẹni Tẹ̀mí ni Jẹ́fútà
Jẹ́fútà ò di àwọn ọmọ bàbá ẹ̀ sínú (Ond 11:5-9; w16.04 5 ¶9)
Jẹ́fútà kẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn nǹkan tí Jèhófà ti ṣe fáwọn èèyàn rẹ̀ nígbà àtijọ́ (Ond 11:12-15; it-2 27 ¶2)
Ohun tó ṣe pàtàkì jù sí Jẹ́fútà ni báwọn èèyàn ṣe máa mọ̀ pé Jèhófà ni Ọlọ́run tòótọ́ (Ond 11:23, 24, 27; it-2 27 ¶3)
Àwọn nǹkan wo ni mo lè ṣe tá fi hàn pé ẹni tẹ̀mí ni mí?