ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 July ojú ìwé 2
  • Bí Jèhófà Ṣe Fẹ́ Ká Máa Sin Òun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bí Jèhófà Ṣe Fẹ́ Ká Máa Sin Òun
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Béèyàn Ṣe Lè Dájọ́ Lọ́nà Tó Tọ́
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Aláìní
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Obìnrin
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ẹ̀mí Èèyàn Ṣeyebíye Lójú Jèhófà
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 July ojú ìwé 2

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bí Jèhófà Ṣe Fẹ́ Ká Máa Sin Òun

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbọ́dọ̀ máa ṣe ohun tí Jèhófà fẹ́, kí wọ́n nífẹ̀ẹ́ rẹ̀, kí wọ́n sì fi gbogbo ọkàn wọn àti gbogbo ara wọn sìn ín (Di 11:13; it-2 1007 ¶4)

Gbogbo ohun tó bá jẹ mọ́ ìsìn èké ni wọ́n gbọ́dọ̀ pa run pátápátá (Di 12:2, 3)

Ibi tí Jèhófà bá yàn ni gbogbo wọn ti gbọ́dọ̀ jọ́sìn (Di 12:11-14; it-1 84 ¶3)

Jèhófà fẹ́ káwọn èèyàn òun máa sin òun tọkàntọkàn, kí wọ́n sá fún ìsìn èké, kí wọ́n sì wà níṣọ̀kan.

Àwòrán: Àwọn tó ń jọ́sìn Ọlọ́run lọ́nà tó fẹ́. 1. Arábìnrin àgbàlagbà kan ń wàásù fún ẹni tó ń tọ́jú ẹ̀. 2. Ọkùnrin kan ń dáná sun àwọn nǹkan tó jẹ mọ́ ìbẹ́mìílò. 3. Àwọn arábìnrin mẹ́tà tí àwọ̀ wọn yàtọ̀ síra ń gbádùn àpéjọ àgbáyé pa pọ̀.
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́