ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Òfin Tí Jèhófà Ṣe Fi Hàn Pé Ó Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Obìnrin
Ọkùnrin kan ò gbọ́dọ̀ lọ sójú ogun lọ́dún àkọ́kọ́ tó bá gbéyàwó (Di 24:5; it-2 1196 ¶4)
Jèhófà máa ń pèsè ohun táwọn opó nílò (Di 24:19-21; it-1 963 ¶2)
Jèhófà ṣètò pé kí wọ́n ṣú obìnrin tí ọkọ rẹ̀ kú lópó kó lè bímọ (Di 25:5, 6; w11 3/1 23)
BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè bọ̀wọ̀ fáwọn obìnrin, kí n sì máa gba tiwọn rò nínú ìdílé àti nínú ìjọ?’