ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb23 November ojú ìwé 2
  • November 6-12

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • November 6-12
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2023
mwb23 November ojú ìwé 2

November 6-12

JÓÒBÙ 13-14

  • Orin 151 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Tí Èèyàn Bá Kú, Ṣé Ó Tún Lè Wà Láàyè?”: (10 min.)

  • Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)

    • Job 13:12—Kí nìdí tí Jóòbù fi sọ pé ọ̀rọ̀ àwọn olùtùnú èké rẹ̀ jọ “òwe tó dà bí eérú”? (it-1 191)

    • Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 13:​1-28 (th ẹ̀kọ́ 12)

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Bíbélì—2Ti 3:​16, 17. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì dáhùn àwọn ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìbẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Bíbélì. (th ẹ̀kọ́ 2)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ohun tó o kọ́ ní apá 1 ìbéèrè 1-5 (th ẹ̀kọ́ 19)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 127

  • “Kí Kálukú Yín Ya Ohun Kan Sọ́tọ̀”: (15 min.) Ìjíròrò àti fídíò. Alàgbà ni kó ṣe iṣẹ́ yìí. Gbóríyìn fáwọn ará fún bí wọ́n ṣe ń ya àwọn owó kan sọ́tọ̀ láti fi ti iṣẹ́ Jèhófà lẹ́yìn.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 1 ¶16-21

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 76 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́