November Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé, November-December 2023 November 6-12 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Tí Èèyàn Bá Kú, Ṣé Ó Tún Lè Wà Láàyè?” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI “Kí Kálukú Yín Ya Ohun Kan Sọ́tọ̀” November 13-19 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Má Ṣe Sọ̀rọ̀ Bíi Élífásì Tó O Bá Ń Tu Àwọn Èèyàn Nínú November 20-26 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Má Ṣe Pa Àwọn Tẹ́ Ẹ Jọ Ń Sin Jèhófà Tì MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ètò Tá A Ṣe Láti Tu Àwọn Tó Wà ní Bẹ́tẹ́lì Nínú November 27–December 3 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Owó Kọ́ Ló Ń Mú Kéèyàn Jẹ́ Olódodo MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ “Jẹ́ Kí Àwọn Nǹkan Tó Wà Báyìí Tẹ́ Yín Lọ́rùn” December 4-10 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN “Ṣé Èèyàn Wúlò fún Ọlọ́run?” MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín Kí Wọ́n Lè Múnú Jèhófà Dùn December 11-17 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Kò Dìgbà Tá A Bá Jẹ́ Ẹni Pípé Ká Tó Lè Jẹ́ Olóòótọ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Jẹ́ Olóòótọ́ Nínú Èrò Rẹ December 18-24 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Ṣé O Ní Orúkọ Rere Bíi Ti Jóòbù? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Ohun Tí Mo Lè Ṣe Táá Jẹ́ Ká Túbọ̀ Lórúkọ Rere December 25-31 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN Bí Jóòbù Ṣe Fi Hàn Pé Òun Jẹ́ Oníwà Mímọ́ MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Kí Nìdí Tí Wíwo Àwòrán Ìṣekúṣe Fi Burú? MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ